"Orukọ Oluwa, ile-iṣọ agbara ni: Olododo sá wọ inu rẹ̀, o si là."    ~Iwe Owe (Proverbs) 18:10~
Oro iki ni kaabo (Welcome)Nipa wa (About Us)Nipa ile ise iranse yi (About the Ministry)Darapo mo ise yi (Be part of this work)A ti ba wa soro (Contact Us)

"Orukọ Oluwa, ile-iṣọ agbara ni: Olododo sá wọ inu rẹ̀, o si là."    ~Iwe Owe (Proverbs) 18:10~
Lati ni ipin ati lati se iranlowo fun ise ihinrere yi, e le lo paypal la ti fi da owo fun ilosiwaju ise yi.  Adupe lowo yin fun ohun kohun ti e fi sile lati se iranlowo.  Olorun awon omo ogun Isreali yio gbe iranlowo dide fun eyin ati idile yin. Maa yo ninu Oluwa wa, nitori pe wakati iyanu ti re naa ti de latoni!
WA DARAPO MO ISE IHINRERE YI
OHUN ELO FUN ITESIWAJU NINU ADURA ATI ISEGUN
Ti e ko ba si ni ibi ise iranse ti Wakati Iyanu ti o koja sehin, e le woo ni ori ero Ustream tabi Youtube ti ati pese ni'bi yi.
"O dara lati ka Bibeli re l'ojojumo fun idagba soke ninu emi!"
Gbọ́ adura mi, Ọlọrun; fi eti si ọ̀rọ ẹnu mi.  (Orin Dafidi 54:2)