BI E TI SE LE RI WA BA SORO 
(To contact Us):



Ile iwe ifiwe ranse wa: 
 Wakati Iyanu Prayer Ministries,
Attn: Pastor & Lady Evang. Z.O.Oloba, 
P.O.Box 391693, Snellville, GA 30039.

Email: aduralolese@gmail.com   
          wakatiiyanu@gmail.com

Ero ibanisoro wa: 404-597-1270 (USA).


LEKAN SI, AWON ETO ILE ISE IRANSE WA NI WONYI:

Ojo Isegun (Tuesdays): Ni gbogbo Ojo Isegun ni a maa nse ipade adura ti akole re nje “Wakatiiyanu Temi” ni ori ero ibanisoro ni dede agogo mesan ale (9pm est) pelu awon Iranse Olorun miran ti o ni ifami ororo yan.

Osu merin – merin (quarterly program): Ipade ati ipago “Mofebo” maa nwaiye ni Jimoh Keta ninu osu (February, July ati November) ni Ilu Atlanta, bere lati agogo mewa ale (10pm est). 

Olorun Iyaanu ni Olorun
Wakati Iyanu!
"Orukọ Oluwa, ile-iṣọ agbara ni: Olododo sá wọ inu rẹ̀, o si là."    ~Iwe Owe (Proverbs) 18:10~
Oro iki ni kaabo (Welcome)Nipa wa (About Us)Nipa ile ise iranse yi (About the Ministry)Darapo mo ise yi (Be part of this work)A ti ba wa soro (Contact Us)

Gbọ́ adura mi, Ọlọrun; fi eti si ọ̀rọ ẹnu mi.  (Orin Dafidi 54:2)