A ki gbogbo enyin Omo Olorun kaabo si Ile Ise Iranse yi, eyi ti Oluwa gbe kale fun idande ati itusile kuro ninu gbogbo ide esu, ota, ese, ati aiye ti a npe akole re ni “Mofebo ati Wakati Iyanu”. Mo gbadura ni oruko Jesu pe gbogbo wa ni yio bo lowo ogun esu ati aiye. Wakati ati akoko iyanu ti Olorun ti seto fun emi ati eyin ko ni ye, sugbon yio was si imuse loruko Jesu Kristi (Amin).
Gbogbo eniyan ni o ni anfani lati wonu ero aiyelujara yi fun awon eto Adura itusile ati oro Olorun ti a ti owo Emimimo dari. Nitorina, a ki yin kaabo leekan si. Ki alaafia Oluwa Olorun awon Omo Ogun ma ba yin gbe titi lai (Amin).
Ile iwe ifiwe ranse wa:
Wakati Iyanu Prayer Ministries,
Attn: Pastor & Lady Evang. Z.O. Oloba,
P.O.Box 391693, Snellville, GA 30039.
Email: aduralolese@gmail.com
wakatiiyanu@gmail.com
Ero ibanisoro wa: 404-597-1270 (USA).
"Orukọ Oluwa, ile-iṣọ agbara ni: Olododo sá wọ inu rẹ̀, o si là." ~Iwe Owe (Proverbs) 18:10~
"Ẹmí li Ọlọrun: awọn ẹniti nsìn ko le ṣe alaisìn li ẹmí ati li otitọ"
~John 4:24~
Gbọ́ adura mi, Ọlọrun; fi eti si ọ̀rọ ẹnu mi. (Orin Dafidi 54:2)
UPCOMING EVENTS
(ETO ESIN TO N'BO)
>>CLICK IMAGE TO VIEW FLIER<<
(>>TE AWORAN YI<<)